Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÌBÉÈRÈ 20

Báwo Lo Ṣe Lè Ka Bíbélì Kó Sì Ṣe Ọ́ Láǹfààní?

DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ BÍ O ṢE Ń KA BÍBÉLÌ RẸ:

Kí lohun tí mò ń kà yìí jẹ́ kí n mọ̀ nípa Jèhófà Ọlọ́run?

Báwo ni apá ibi tí mo kà nínú Ìwé Mímọ́ yìí ṣe tan mọ́ àkòrí Bíbélì?

Báwo ni mo ṣe lè fi ohun tí mo kà yìí ṣèwà hù nígbèésí ayé mi?

Báwo ni mo ṣe lè fi àwọn ẹsẹ yìí ran ẹlòmíì lọ́wọ́?

“Ọ̀rọ̀ rẹ jẹ́ fìtílà fún ẹsẹ̀ mi àti ìmọ́lẹ̀ fún ọ̀nà mi.”

Sáàmù 119:105