Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìsọfúnni Nípa Wa—Kárí Ayé

  • 239—Iye àwọn ilẹ̀ tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ń jọ́sìn

  • 8,699,048—Iye àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

  • 5,666,996—Iye àwọn èèyàn tí à ń kọ́ ní ẹ̀kọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́

  • 19,721,672—Iye àwọn tó wá sí Ìrántí Ikú Kristi tí à ń ṣe lọ́dọọdún

  • 117,960—Iye ìjọ

 

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Kárí ayé là ń gbé, oríṣiríṣi ẹ̀yà la ti wá, àṣà ìbílẹ̀ wa sì yàtọ̀ síra. O lè ti rí i pé a máa ń wàásù, àmọ́ a tún máa ń ṣèrànwọ́ láwùjọ láwọn ọ̀nà pàtàkì míì.

Tún Wo

ÌWÉ ŃLÁ ÀTI ÌWÉ PẸLẸBẸ

Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé ti Ọdún 2022

Wàá rí ìròyìn nípa iṣẹ́ ìwàásù àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà láti September 2021 sí August 2022.

ILÉ ÌṢỌ́

Ta Ni Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Ṣé èrò àwọn tá a mẹ́nu kàn nínú àpilẹ̀kọ yìí bá tìẹ mu?