Ohun Tuntun Wo Ló Wà ní JW.ORG?
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Gbólóhùn Kan Látinú Bíbélì—“Tó Bá Ṣeé Ṣe, . . . Ẹ Wà Ní Àlàáfíà Pẹ̀lú Gbogbo Èèyàn”
Àwọn Kristẹni tòótọ́ máa ń gbìyànjú láti wà ní àlàáfíà pẹ̀lú gbogbo èèyàn, àmọ́ nígbà mí ì kì í rọrùn láti ṣe bẹ́ẹ̀. Kí nìdí?
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Àwọn Nǹkan Mẹ́ta Táá Jẹ́ Kó O Lè Máa Gbàdúrà Tó Gùn
Kí lo lè ṣe kó o lè ráyè gbàdúrà tó gùn kó o lè sọ gbogbo ohun tó wà lọ́kàn ẹ, àti bí nǹkan ṣe rí lára ẹ fún Jèhófà?
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Àǹfààní Tó O Máa Rí Tó O Bá Ń Wáyè Dá Wà
Wàá rí bí Jésù ṣe wáyè kó lè dá wà, àti ìdí tó fi yẹ kíwọ náà ṣe bẹ́ẹ̀.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Ǹjẹ́ O Rántí?—December 2026
Ṣé o gbádùn àwọn Ilé Ìṣọ́ tó jáde lẹ́nu àìpẹ́ yìí? Wò ó bóyá o lè rántí àwọn nǹkan tó o kọ́.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
December 2026
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti February 1-28, 2027 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Josette Garcia: Ọ̀pọ̀ Ọdún Ni Mo Fi Wàásù ní Ọ̀kan Lára Àwọn Orílẹ̀-Èdè tí Ojú Ọjọ́ Ibẹ̀ Gbóná Jù Láyé
Ọ̀pọ̀ ìṣòro ni Josette kojú ní Mali, àmọ́ ó láyọ̀ ní gbogbo ọdún tó fi ṣe aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe àti míṣọ́nnárì níbẹ̀.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Ohun Tó O Lè Fi Kẹ́kọ̀ọ́—Ohun Tó O Lè Ṣe Káwọn Fídíò Wa Lè Túbọ̀ Ṣe Ẹ́ Láǹfààní
Wàá rí àwọn ohun tó o lè ṣe káwọn fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org lè túbọ̀ ṣe ẹ́ láǹfààní.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Mọyì Bí Ìwà Gbogbo Àwọn Tó Wà Nínú Ìjọ Ṣe Yàtọ̀ Síra
Kí lá jẹ́ ká mọyì ìwà ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ táwọn ará wa lọ́kùnrin àti lóbìnrin ní àti bí kálukú wọn ṣe ń ronú?
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Báwo làwọn ọmọ ogun tó jẹ́ Ẹ̀ṣọ́ Ọba ṣe máa ń múra?
Wàá rí bí àwùjọ ọmọ ogun tó lákíkanjú ṣe ń múra, àti báwọn èèyàn ṣe lè dá wọn mọ̀.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Bá A Ṣe Lè Nítẹ̀ẹ́lọ́rùn Tí Àtijẹ-Àtimu Bá Ṣòro
Wàá rí àwọn ìlànà Bíbélì mẹ́rin táá jẹ́ kó o nítẹ̀ẹ́lọ́rùn láìka ipò yòówù kó o wà sí.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
November 2026
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti January 4-31, 2027 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÀWỌN ORIN WA MÍÌ
’O Ṣeyebíye Ju Àwọn Ẹyẹ’
O lè máa wọ ara ẹ bíi pé o ò wúlò, àmọ́ ojú tí Jèhófà fi ń wò ẹ́ kọ́ nìyẹn. Tí irú èrò yẹn bá ń wá sí ẹ lọ́kàn, fídíò orin yìí ń rán wa létí pé a ṣeyebíye gan-an lójú Jèhófà àtàwọn ará wa.

