Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìrírí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń gbìyànjú láti fi Bíbélì, Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run darí ohun tí wọ́n ń rò, ọ̀rọ̀ wọn àti ìṣe wọn. Wo ìyípadà tó mú kó ṣẹlẹ̀ nínú ayé wọn àtàwọn tó wà láyìíká wọn.

ÌRÍRÍ

Sọ fún Wọn Pé O Nífẹ̀ẹ́ Wọn

Kọ́ nípa bí Bíbélì ṣe ran ìdílé kan lọ́wọ́ tí wọ́n fi túbọ̀ nífẹ̀ẹ́ ara wọn, tí ilé wọn sì túbọ̀ tòrò.

ÌRÍRÍ

Sọ fún Wọn Pé O Nífẹ̀ẹ́ Wọn

Kọ́ nípa bí Bíbélì ṣe ran ìdílé kan lọ́wọ́ tí wọ́n fi túbọ̀ nífẹ̀ẹ́ ara wọn, tí ilé wọn sì túbọ̀ tòrò.

Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà