Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ṣé O Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá?

Ṣé wàá fẹ́ mọ̀ sí i nípa Bíbélì tàbí nípa àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà? Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i, kọ ọ̀rọ̀ kún fọ́ọ̀mù tó wà nísàlẹ̀ yìí, Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan tó ń gbé ládùúgbò rẹ á sì wá ẹ wá.

A ò ní lo àwọn nǹkan tó o bá kọ sínú fọ́ọ̀mù náà fún ohunkóhun míì ju pé ká fi wá ẹ wá lásìkò tó o bá fẹ́. Èyí sì bá Ìlànà Nípa Lílo Ìsọfúnni Ara Ẹni mu.

Ẹnì Kan Máa Kàn Sí Ẹ

Lẹ́yìn tó o bá ti kọ̀rọ̀ kún fọ́ọ̀mù yìí, ọ̀kan lára àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa kàn sí ẹ láàárín ọ̀sẹ̀ kan sí méjì.

Kẹ́kọ̀ọ́ Látinú Bíbélì

O lè kẹ́kọ̀ọ́ nípa ọ̀pọ̀ nǹkan tó wà nínú Bíbélì tàbí kó o béèrè fún Ìjíròrò Bíbélì tá a máa ń ṣe lọ́fẹ̀ẹ́.

Ó Rọrùn Gan-an

Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa kàn sí ẹ látorí ẹ̀rọ, ó sì lè wá bá ẹ níbi tó o bá fẹ́ àti nígbà tó máa rọ̀ ẹ́ lọ́rùn.

Àjàkálẹ̀ Àrùn Corona: Ní ọ̀pọ̀ ibi, a ò lọ sọ́dọ̀ àwọn èèyàn láti wàásù fún wọn lásìkò yìí. Jọ̀wọ́ kọ nọ́ńbà fóòńù rẹ sínú fọ́ọ̀mù yìí, Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan tó wà ní àdúgbò rẹ máa pè ẹ́.