Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ṣé Ìwà Ibi àti Ìyà Lè Dópin?

Wàá rí ìdáhùn tó o bá jẹ́ káwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà kọ́ ẹ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́.

 

Mọ Púpọ̀ Sí I

Ka Bíbélì Lórí Ìkànnì

Ṣàyẹ̀wò àwọn nǹkan tó wà nínú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí ọ̀rọ̀ inú rẹ̀ péye, tó sì rọrùn kà.

Ka Bíbélì Lórí Ìkànnì

Ṣàyẹ̀wò àwọn nǹkan tó wà nínú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí ọ̀rọ̀ inú rẹ̀ péye, tó sì rọrùn kà.

Wo àwọn fídíò, orin, àpilẹ̀kọ àti ìròyìn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jáde.

Wo Ohun Tuntun

Gbìyànjú Ẹ̀ Wò

Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan lè wá ọ wa láti kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú rẹ lọ́fẹ̀ẹ́.

Ṣé O Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá?

Jẹ́ kí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan fi Bíbélì dáhùn ìbéèrè rẹ tàbí kó ṣàlàyé àwọn nǹkan tí kò yé ẹ nípa àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà fún ẹ.

Lọ sí ìpàdé ìjọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Wàá mọ ohun tá a máa ń ṣe láwọn ìpàdé wa, wàá sì mọ ibi tá a ti ń ṣèpàdé tó sún mọ́ ẹ.

Ta Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

A wá látinú onírúurú ẹ̀yà àti èdè, síbẹ̀ àwọn ohun kan náà ló jẹ gbogbo wa lógún. Olórí gbogbo ẹ̀ ni pé, a fẹ́ bọlá fún Jèhófà, Ọlọ́run tó ni Bíbélì tó sì jẹ́ Ẹlẹ́dàá ohun gbogbo. A ń ṣe gbogbo ohun tá a lè ṣe láti máa tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù Kristi, inú wa sì ń dùn pé a jẹ́ Kristẹni. Ẹnì kọ̀ọ̀kan wa máa ń fi àkókò rẹ̀ ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ kí wọ́n lè kẹ́kọ̀ọ́ nípa Bíbélì àti Ìjọba Ọlọ́run. Àwọn èèyàn mọ̀ wá sí Ẹlẹ́rìí Jèhófà torí pé a máa ń jẹ́rìí nípa Jèhófà Ọlọ́run àti Ìjọba rẹ̀.

Oríṣiríṣi nǹkan lo máa rí lórí ìkànnì yìí. Ka Bíbélì lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì. Mọ púpọ̀ sí i nípa wa àtàwọn ohun tá a gbà gbọ́.

 

Two of Jehovah's Witnesses preaching to a man in a rice paddy.