Yorùbá
Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti Jí!
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1011209/univ/wpub/1011209_univ_sqr_xl.jpg

Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti Jí!

Àwọn ìwé ìròyìn wa tá a gbé ka Bíbélì wà lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì, o lè wà wọ́n jáde ní ọgọ́rọ̀ọ̀rún èdè, èdè àwọn adití náà wà níbẹ̀. Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ ń jẹ́ ká rí bí àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì ṣe ń ṣẹ lónìí. Ó ń fi ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run tu àwọn èèyàn nínú, ó sì ń jẹ́ kéèyàn túbọ̀ nígbàgbọ́ nínú Jésù Kristi. Ìwé ìròyìn Jí! ń jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè fara da àwọn ìṣòro òde òní, ó sì ń mú kó túbọ̀ dá wa lójú pé Ẹlẹ́dàá wa máa mú ayé tuntun wá, níbi tí àlàáfíà àti ààbò máa wà, bó ṣe ṣèlérí.

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

May 2026

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti July 6–August 9, 2026 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

JÍ!

Ohun Méjìlá Tó Ń Mú Kí Ìdílé Láyọ̀

Tó o bá ń tẹ̀ lé àwọn ìlànà yìí, ìdílé rẹ á láyọ̀.

WÒ Ó

JÍ!

JÍ!

JÍ!

JÍ!

JÍ!

ILÉ ÌṢỌ́

ILÉ ÌṢỌ́

ILÉ ÌṢỌ́

ILÉ ÌṢỌ́

ILÉ ÌṢỌ́

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́