Ìsọfúnni Nípa Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba, àwọn akọ̀ròyìn, àwọn olùkọ́ àtàwọn akẹ́kọ̀ọ́ lè rí ìsọfúnni nípa àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti iṣẹ́ tá à ń ṣe.

Wọ́n Fi Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Sẹ́wọ̀n Torí Ohun Tí Wọ́n Gbà Gbọ́ Láwọn Orílẹ̀-Èdè Kan

Àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti fi àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà sẹ́wọ̀n torí pé à ń lo ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn tá a ní lábẹ́ òfin àti torí ohun tá a gbà gbọ́. Nǹkan máa ń nira gan-an fáwọn ará wa kan tí wọ́n fi sẹ́wọ̀n.