Ìsọfúnni Nípa Wa—Kárí Ayé

  • 241—Iye àwọn ilẹ̀ tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ń jọ́sìn

  • 9,205,326—Iye àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

  • 7,603,182—Iye àwọn èèyàn tí à ń kọ́ ní ẹ̀kọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́

  • 20,635,015—Iye àwọn tó wá sí Ìrántí Ikú Kristi tí à ń ṣe lọ́dọọdún

  • 119,652—Iye ìjọ

 

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Kárí ayé là ń gbé, oríṣiríṣi ẹ̀yà la ti wá, àṣà ìbílẹ̀ wa sì yàtọ̀ síra. O lè ti rí i pé a máa ń wàásù, àmọ́ a tún máa ń ṣèrànwọ́ láwùjọ láwọn ọ̀nà pàtàkì míì.

Tún Wo

ILÉ ÌṢỌ́

Ta Ni Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Ṣé èrò àwọn tá a mẹ́nu kàn nínú àpilẹ̀kọ yìí bá tìẹ mu?