Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Aruba

  • San Nicolas, lórílẹ̀-èdè Aruba (January 1950)​—⁠Henry àti Alice Tweed tí wọ́n jẹ́ míṣọ́nnárì, àti Oris Mills, dúró síwájú Ilé Ìpàdé àkọ́kọ́ lórílẹ̀-èdè Aruba. Nígbà tó yá, Oris àti Woodworth ọkọ ẹ̀ lọ ṣiṣẹ́ míṣọ́nnárì lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti St. Lucia fọ́pọ̀ ọdún

  • Etíkun Rodgers, ní erékùṣù Aruba—Wọ́n ń fún ẹnì kan ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!

  • Etíkun Rodgers, ní erékùṣù Aruba—Wọ́n ń fi fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? han ẹnì kan

  • Etíkun Rodgers, ní erékùṣù Aruba—Wọ́n ń fi ọ̀rọ̀ Bíbélì tu àwọn èèyàn nínú

Ìsọfúnni Ṣókí—Aruba

  • 108,000—Iye àwọn èèyàn
  • 1,106—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 13—Iye àwọn ìjọ
  • 99—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún