Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìròyìn

 

ÌRÒYÌN

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2024 #3

Nínú ìròyìn yìí, a máa jíròrò àwọn ìlànà Bíbélì tó máa jẹ́ ká lè ṣèpinnu tó dáa tó bá dọ̀rọ̀ ìmúra wa.

ÌRÒYÌN

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2024 #3

Nínú ìròyìn yìí, a máa jíròrò àwọn ìlànà Bíbélì tó máa jẹ́ ká lè ṣèpinnu tó dáa tó bá dọ̀rọ̀ ìmúra wa.

Ìròyìn Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2024 #2

Nínú ìròyìn yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa bí Jèhófà Baba wa onífẹ̀ẹ́ ṣe fi hàn pé òun “fẹ́ kí gbogbo èèyàn ronú pìwà dà.” (2 Pét. 3:9) Àá tún rí àtúnṣe tá a ṣe nípa ọ̀nà tá a lè gbà múra tá a bá ń lọ sáwọn ìpàdé àti àpéjọ.

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2024 #1

Wàá rí bí ìfẹ́ tá a ní sáwọn èèyàn ṣe máa jẹ́ ká túbọ̀ nítara lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù.

2023-03-20

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2023 #2

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ̀rọ̀ nípa bí nǹkan ṣe ń lọ sí fáwọn ará wa lórílẹ̀-èdè Türkiye, ó sì tún fọ̀rọ̀ wá àwọn arákùnrin kan lẹ́nu wò.

2023-01-10

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2023 #1

A fẹ́ kẹ́ ẹ wo fídíò yìí kẹ́ ẹ lè gbọ́ àwọn ìròyìn amóríyá nípa iṣẹ́ ìkọ́lé Ramapo àti iṣẹ́ ìwàásù àwọn aṣáájú-ọ̀nà.

2022-11-18

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #7

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí gbà wá níyànjú pé ká má ṣe máa fi nǹkan falẹ̀ nígbà tí ewu bá ń rọ̀ dẹ̀dẹ̀ lágbègbè wà.

2022-12-19

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #6

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ àwọn ohun tó ṣẹlẹ̀ lẹ́nu àìpẹ́ yìí, ó sì jẹ́ ká mọ ohun tó máa jẹ́ ẹsẹ Ìwé Mímọ́ ọdún 2023.

2022-11-18

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #5

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí jẹ́ ká mọ ohun tó ran àwọn ará wa tó wà ní Soviet Union lọ́wọ́ láti jẹ́ adúróṣinṣin láìka inúnibíni tí wọ́n dojú kọ sí, wọ́n sì jẹ́ kó dá wa lójú pé Jèhófà á máa tì wá lẹ́yìn.

2022-04-23

ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #3

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí jẹ́ ká mọ àwọn nǹkan tá a lè ṣe tá ò fi ní máa kọ́kàn sókè torí ogun tó ń jà lápá ìlà oòrùn Yúróòpù.

Wọ́n Fi Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Sẹ́wọ̀n Torí Ohun Tí Wọ́n Gbà Gbọ́​—Ibì Kọ̀ọ̀kan

Àwọn ibi tí wọ́n ti fi àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sẹ́wọ̀n torí wọ́n ń ṣe ohun tí wọ́n gbà gbọ́, wọ́n sì ń lo ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn tí wọ́n ní. Wọ́n máa ń hùwà ìkà sí wọn lẹ́wọ̀n nígbà míì.