Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ọ̀ràn Ẹjọ́ àti Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn

Ọ́fíìsì Àwọn Amòfin

Àdírẹ́sì tó o lè fìwé ráńṣẹ́ sí àti nọ́ńbà fóònù ọ́fíìsì àwọn amòfin wa.

Wọ́n Fi Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Sẹ́wọ̀n Torí Ohun Tí Wọ́n Gbà Gbọ́​—Ibì Kọ̀ọ̀kan

Àwọn ibi tí wọ́n ti fi àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sẹ́wọ̀n torí wọ́n ń ṣe ohun tí wọ́n gbà gbọ́, wọ́n sì ń lo ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn tí wọ́n ní. Wọ́n máa ń hùwà ìkà sí wọn lẹ́wọ̀n nígbà míì.

Articles