Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Watchtower Library

Watchtower Library

Àkójọ àwọn Bíbélì àtàwọn ìwé àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ló wà nínú Watchtower Library. Wàá rí ìwé gbédègbẹ́yọ̀ Insight on the Scriptures níbẹ̀, tó fi mọ́ àwọn ìwé ńlá, ìwé pẹlẹbẹ, àṣàrò kúkúrú àtàwọn ìwé ìròyìn. Wàá tún rí àwọn ohun tó o lè fi ṣèwádìí, bí ìwé Watch Tower Publications Index àti Ìwé Ìwádìí fún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. O lè wá ọ̀rọ̀, gbólóhùn tàbí ẹsẹ Bíbélì nínú èyíkéyìí lára àwọn ìtẹ̀jáde yìí.

Wa Watchtower Library Tó Dé Kẹ́yìn Jáde

Ṣe Watchtower Library lọ́nà tó fi máa wo orí ìkànnì fúnra rẹ̀ bóyá ohun tuntun ti wà, tàbí kó o fi fáìlì tó ní àwọn ohun tuntun náà gbé àwọn ìwé àti àpilẹ̀kọ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ dé sórí Watchtower Library fúnra rẹ láìlo íńtánẹ́ẹ̀tì.

Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè—Watchtower Library

Wàá rí ìdáhùn ìbéèrè tí àwọn èèyàn sábà máa ń béèrè.