Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọ́run
gbàgbọ́ jẹ́ ohun tó lágbára gan-an tó lè mú káyé ẹni dára. Ó lè jẹ́ kó o ní ìbàlẹ̀ ọkàn ní báyìí, kó o sì tún ní ìrètí tó dájú fún ọjọ́ ọ̀la. Bóyá o kò gba Ọlọ́run gbọ́ ní o, àbí oò nígbàgbọ́ bíi ti tẹ̀lẹ́ mọ́, tàbí kẹ̀, tóo bá fẹ́ kí ìgbàgbọ́ rẹ túbọ̀ lágbára sí i, Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́.
ILÉ ÌṢỌ́
Ǹjẹ́ A Lè Mọ Ọlọ́run?
Àwọn nǹkan tí a kò mọ̀ nípa Ọlọ́run lè mú kó o túbọ̀ sún mọ́ Ọlọ́run sí i.
ILÉ ÌṢỌ́
Ǹjẹ́ A Lè Mọ Ọlọ́run?
Àwọn nǹkan tí a kò mọ̀ nípa Ọlọ́run lè mú kó o túbọ̀ sún mọ́ Ọlọ́run sí i.
Bí Ìgbàgbọ́ Rẹ Nínú Ọlọ́run Ṣe Lè Lágbára
Àdúrà
Kíka Bíbélì àti Kíkẹ́kọ̀ọ́ Rẹ̀
Bí Èèyàn Ṣe Lè Fìwà Jọ Ọlọ́run
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—Àwọn Ọkùnrin àti Obìnrin Tí Bíbélì Sọ̀rọ̀ Nípa Wọn
Ìtẹ̀jáde
Ìgbàgbọ́ Òdodo Ló Máa Mú Kó O Ní Ayọ̀
Ìwé pẹlẹbẹ yìí ṣàlàyé bí àwọn èèyàn láti onírúurú ilẹ̀ ṣe lè láyọ̀ tí wọ́n bá lè mú kí ìgbàgbọ́ wọn jinlẹ̀.