Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Bí Èèyàn Ṣe Lè Fìwà Jọ Ọlọ́run

Bó O Ṣe Lè Sunwọ̀n Sí i

Ohun Tó Ń Fúnni Láyọ̀​—Ìtẹ́lọ́rùn àti Ìwà Ọ̀làwọ́

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló gbà pé bí àwọ́n bá ṣe lówó tó ni àwọn ṣe máa láyọ̀ tó. Àmọ́ ṣé owó àti ohun ìní rẹpẹtẹ ló ń fúnni ní ojúlówó ayọ̀? Kí ni ẹ̀rí fi hàn?

Èrè Tó Wà Nínú Fífúnni Ní Nǹkan

Fífúnni ní nǹkan máa mú èrè wá fún ẹ àtàwọn mí ì. Ó máa ń jẹ́ kí àjọṣe tó dáa wà láàárín àwọn èèyàn. Báwo lo ṣe lè ní ẹ̀mí fífúnni?

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ẹ̀mí Ìmoore?

Ọ̀pọ̀ àǹfààní ló wà nínú kéèyàn jẹ́ ẹni tó moore. Àǹfààní wo ló wà níbẹ̀ àti pé báwo lo ṣe lè ní irú ẹ̀mí yẹn?

Jẹ́ Oníwà Tútù​—Ohun Tó Bọ́gbọ́n Mu Ni

Kò rọrùn láti gba ìwọ̀sí mọ́ra, síbẹ̀ Bíbélì rọ àwa Kristẹni pé ká jẹ́ oníwà tútù. Kí ló máa jẹ́ kó o níwà tútù?

Ohun Tó Ń Fúnni Láyọ̀​—⁠Ìdáríjì

Tí ìgbésí ayé ẹni bá kún fún ìbínú ní gbogbo ọjọ́, téèyàn sì ń gbé ọ̀rọ̀ sọ́kàn, èèyàn ò ní láyọ̀, ìlera rẹ̀ ò sì ní dára.

Àǹfààní Tó Wà Nínú Jíjẹ́ Olóòótọ́

Ohun tó ṣẹlẹ̀ sáwọn kan jẹ́ ká rí àǹfààní tó wà nínú jíjẹ́ olóòótọ́.

Ṣé Ohun Kan Wà Tó Burú Tàbí Dára?

Wàá rí ìdí méjì tó fi yẹ ká gbára lé àwọn ìlànà Bíbélì.

Àjọṣe Tó Dáa Pẹ̀lú Àwọn Míì

Ìkórìíra​—Máa Fìfẹ́ Hàn Sáwọn Èèyàn

Tá a bá ń fìfẹ́ hàn sáwọn èèyàn, ẹ̀tanú àti ẹ̀mí ìkórìíra máa kúrò lọ́kàn wa. Wo àwọn nǹkan tó máa ràn wá lọ́wọ́.

Ohun Tó Ń Fúnni Láyọ̀​—Ìfẹ́

Èèyàn máa láyọ̀ tí wọ́n bá ń fi ìfẹ́ hàn síni téèyàn sì ń fi ìfẹ́ hàn sáwọn ẹlòmí ì.

Nje Bibeli Wulo fun Wa Lonii?—Ife

Ife ti Bibeli saba maa n menu kan ki i se ife aarin lokotaya.

Inú Rere Ṣe Pàtàkì Lójú Ọlọ́run

Ṣé ó yẹ kó o máa fi inú rere hàn sí gbogbo èèyàn. Ojú wo ni Ọlọ́run fi ń wo ànímọ́ yìí?

Bí Ẹ Ṣe Lè Mú Kí Àlàáfíà Wà Nínú Ilé

Ṣé àwọn ìmọ̀ràn Bíbélì lè mú kí àlàáfíà wà níbi tí kò sí tẹ́lẹ̀? Wo ohun táwọn tó ti fi ìmọ̀ràn Bíbélì sílò sọ.

Máa Dárí Jini Látọkànwá

Tá a bá fẹ́ dárí jini, ṣé ká kàn fojú pa ohun tẹ́nì kan ṣe rẹ́ tàbí ká ṣe bíi pé kò dùn wá?

Bó o Ṣe Lè Kápá Ìbínú Rẹ

Tó o bá ń gbaná jẹ, ó lè ṣàkóbá fún ìlera rẹ, tó o bá tún lọ ń di ìbínú sínú ìyẹn náà máa ṣàkóbá fún ẹ. Torí náà kí lo lè ṣe tí ọkọ tàbí ìyàwó rẹ bá múnú bí ẹ gan-an?