Yorùbá
Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Ọ̀dọ́
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1011206/univ/art/1011206_univ_sqr_xl.jpg

Ọ̀dọ́

A ti yí díẹ̀ lára orúkọ àwọn tá a fa ọ̀rọ̀ wọn yọ nínú àwọn àpilẹ̀kọ yìí pa dà.

ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ

Àkóbá Wo Ni Ìkànnì Àjọlò Lè Ṣe fún Mi?

Lílo ìkànnì àjọlò lè di bárakú. Àwọn àbá yìí lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó má bàa kó bá ẹ.

ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ

Àkóbá Wo Ni Ìkànnì Àjọlò Lè Ṣe fún Mi?

Lílo ìkànnì àjọlò lè di bárakú. Àwọn àbá yìí lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó má bàa kó bá ẹ.

Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé

Àwọn ìbéèrè tí àwọn ọ̀dọ́ sábà máa ń béèrè nípa ìbálòpọ̀, àwọn ọ̀rẹ́ wọn, àwọn òbí wọn, iléèwé àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ

Ó ṣeé ṣe kí o ní ìṣòro kan tó ò ní rí. Wo bí àwọn ọ̀dọ́ bíi tìẹ ṣe ń borí irú ẹ̀.

Àwọn Eré Ojú Pátákó

Ṣé o máa ń ní àwọn ìṣòro tó dà bíi pé agbára rẹ ò ká? Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, àwọn fídíò kékeré yìí lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí àwọn ìṣòro tí àwọn ọ̀dọ́ sábà máa ń ní.

Ìwé Àjákọ fún Àwọn Ọ̀dọ́

Àwọn ìwé àjákọ yìí á jẹ́ kó o lè kọ èrò rẹ sílẹ̀, á jẹ́ kó o mo ohun tó o máa ṣe tó o ba ní ìṣòro.

Eré Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

Àwọn ẹ̀kọ́ tó ṣeé tẹ̀ jáde tó máa jẹ́ ká máa fojú inú wo àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ inú Bíbélì bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́.

Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè 10 Táwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè

Tẹ̀ lé àwọn ìmọ̀ràn àti àbá tó lè mú kí ìgbésí ayé ẹ dáa.

Atọ́nà Ìkẹ́kọ̀ọ́

Fi àwọn atọ́nà ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí ṣàyẹ̀wò ohun tó o gbà gbọ́ kó lè túbọ̀ dá ẹ lójú, kó o sì fi kọ́ bó o ṣe lè ṣàlàyé ohun tó o gbà gbọ́.