Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Eré Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

A ṣe àwọn ẹ̀kọ́ yìí láti ran àwọn ọ̀dọ́ lọ́wọ́ kí wọ́n lè lóye Bíbélì. Wa ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!