ABALA ÀWỌN Ọ̀DỌ́
Adẹ́tẹ̀ Kan Rí Ìwòsàn Gbà!
Kẹ́kọ̀ọ́ látinú ìtàn Bíbélì nípa bí ọmọbìnrin Ísírẹ́lì kan ṣe ran olórí ẹgbẹ́ ọmọ ogun Síríà kan lọ́wọ́ kó lè rí ìwòsàn. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!