Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ABALA ÀWỌN Ọ̀DỌ́

Ọkùnrin Onírẹ̀lẹ̀ àti Onígboyà

Kẹ́kọ̀ọ́ látinú àpẹẹrẹ Jónà. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!