Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ

Mósè Gba Iṣẹ́ Pàtàkì Kan

Bó tiẹ̀ níbi tágbára wa mọ, kọ́ bí a ṣe lè wúlò fún Jèhófà. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!