Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ

Má Ṣe Gba Àwọn Ẹ̀mí Burúkú Láyè!

Kẹ́kọ̀ọ́ nínú Bíbélì nípa bó ò ṣe ní gba àwọn ẹ̀mí búburú láyè. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!