Yorùbá
Ọlọ́run Gbà Wọ́n Kúrò Nínú Ìléru Oníná!
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502012447/univ/art/502012447_univ_sqr_xl.jpg

ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ

Ọlọ́run Gbà Wọ́n Kúrò Nínú Ìléru Oníná!

Kẹ́kọ̀ọ́ látinú ìtàn Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dínígò. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!