Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Orin fún Ìjọsìn Kristẹni

Wa àwọn orin Kristẹni tó dùn gan-an jáde. A máa ń fi wọ́n yin Jèhófà Ọlọ́run, a sì tún ń fi wọ́n jọ́sìn rẹ̀. Àwọn orin tá a fẹnu kọ àtàwọn tá a fi oríṣiríṣi ohun èlò ìkọrin kọ wà níbẹ̀.

 

“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà

Àwọn Orin Wa Míì

Kọrin sí Jèhófà