Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè Nípa Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Ṣé Kristẹni Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Jọ̀wọ́ ṣàgbéyẹ̀wò bí a ṣe yàtọ̀ sí àwọn míì tí wọ́n ń pè ní Kristẹni.

Ṣé Kristẹni Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Jọ̀wọ́ ṣàgbéyẹ̀wò bí a ṣe yàtọ̀ sí àwọn míì tí wọ́n ń pè ní Kristẹni.

Báwo Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣe Ń Lo Àwọn Ọrẹ Tá À Ń Rí?

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí máa ń lo ọrẹ tí wọ́n ń gbà láti sọ ara wọn di olówó?

Kí Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gbà Gbọ́?

Ní ṣókì, wo ohun mẹ́ẹ̀ẹ́dógún [15] tá a gbà gbọ́.

Ǹjẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Jésù?

Ẹ ṣàgbéyẹ̀wò ìdí tó fi ṣe pàtàkì káwọn Kristẹni tòótọ́ nígbàgbọ́ nínú Jésù.

Ǹjẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gbà Pé Ẹ̀sìn Àwọn Lẹ̀sìn Tòótọ́?

Ǹjẹ́ Jésù sọ pé ọ̀pọ̀ ọ̀nà ló ń ṣamọ̀nà sí ìgbàlà?

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Fàyè Gba Àwọn Ẹ̀sìn Míì?

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bí fífàyè gba àwọn míì ṣe ń jẹ́ ká mọ àwọn Kristẹni tòótọ́.

Ṣé Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tako Gbígba Abẹ́rẹ́ Àjẹsára?

Ìlànà Bíbélì méjì kan wà tá a lè ronú lé tá a bá fẹ́ pinnu bóyá ká gba abẹ́rẹ́ àjẹsára tàbí ká má ṣe bẹ́ẹ̀.

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ka Sáyẹ́ǹsì Sí?

Ṣé ohun tí wọ́n gbà gbọ́ àtàwọn ohun táwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì sọ bára mu?

Kí Ló Fà Á Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Fi Yí Àwọn Ohun Kan tí Wọ́n Gbà Gbọ́ Pa Dà?

Kò yẹ kí àwọn àyípadà yìí yani lẹ́nu. Láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì náà, àwọn ìgbà kan wà tí àwọn tó ń sin Ọlọ́run ní láti yí èrò wọn pa dà.

Kí Nìdí Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kì í Fi Lo Àgbélébùú Nínú Ìjọsìn?

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé Kristẹni ni wá, a kì í lo àgbélébùú nínú ìjọsìn wa. Kí nìdí?

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Ṣe Àmúlùmálà Ìgbàgbọ́?

Kí ni Bíbélì sọ tí wọ́n lè fi dáhùn ìbéèrè yìí?

Báwo Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣe Ń Lo Àwọn Ọrẹ Tá À Ń Rí?

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí máa ń lo ọrẹ tí wọ́n ń gbà láti sọ ara wọn di olówó?

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Mélòó Ló Wà Kárí Ayé?

Wo bá a ṣe máa ń ka iye wa nínú àwọn ìjọ wa kárí ayé.

Ta Ló Dá Ẹ̀sìn Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Sílẹ̀?

Kà nípa ìdí tí Charles Taze Russell kì í fi í ṣe olùdásílẹ̀ ẹ̀sìn tuntun kan.

Ibo Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Ń Rówó Tí Wọ́n Ń Ná?

A ò kì í gba owó báwọn oníṣọ́ọ̀ṣì ṣe ń gba owó.

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Àwọn Àlùfáà Tí Wọ́n Ń Sanwó Fún?

Ṣé ẹ ní ẹgbẹ́ àwọn àlùfáà àti ti ọmọ ìjọ? Àwọn wo ni òjíṣẹ́?

Báwo Ní Ẹ Ṣe Ń Ṣètò Ìjọ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Wádìí bá a ṣe ń rí ìtọ́ni àti ìtọ́sọ́nà gbà nípasẹ̀ ìṣètò yìí.

Kí Là Ń Pè Ní Ìgbìmọ̀ Olùdarí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Ṣé àwọn tó wà nínú ìgbìmọ̀ yìí ni olórí wa?

Kí Ni Watch Tower Bible and Tract Society?

Báwo ni àwọn àjọ tá a dá sílẹ̀ lábẹ́ òfin yìí ṣe tan mọ́ iṣẹ́ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Kí Nìdí Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kì Í Fèsì Gbogbo Ẹ̀sùn Táwọn Èèyàn Fi Ń Kàn Wọ́n?

Táwọn èèyàn bá fẹ̀sùn kan àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tàbí tí wọ́n bi wọ́n ní ìbéèrè, ìlànà Bíbélì ni wọ́n máa ń tẹ̀ lé kí wọ́n lè mohun tí wọ́n á ṣe. Wọ́n máa ń wò ó bóyá “ìgbà dídákẹ́ jẹ́ẹ́” ni àbí “ìgbà sísọ̀rọ̀.”​—Oníwàásù 3:7.

Kí Nìdí Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Fi Ń Lọ Láti Ilé Dé Ilé?

Kọ́ nípa ohun tí Jésù sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀ pé kí wọ́n máa ṣe.

Ṣé Torí Kẹ́ Ẹ Lè Jèrè Ìgbàlà Lẹ Ṣe Ń Wàásù Látilé Délé?

Ka ohun tá a gbà gbọ́ nípa ìgbàlà àti béèyàn ṣe lè rí i gbà.

Kí Nìdí Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Fi Ń Lọ Sọ́dọ̀ Àwọn Èèyàn Tó Ti Lẹ́sìn Tiwọn?

Kí ló ń mú ká máa lọ sọ́dọ̀ àwọn èèyàn tó ti lẹ́sìn tiwọn?

Ṣé Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Fipá Mú Káwọn Èèyàn Yí Ẹ̀sìn Wọn Pa Dà?

Ṣé torí àtiyí àwọn èèyàn lẹ́sìn pa dà làwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe ń wàásù? Ṣé wọ́n fẹ́ fipá yí àwọn míì lẹ́sìn pa dà ni?

Kí Ni Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn?

Ìtumọ̀ Bíbélì èyíkéyìí tó bá wù ẹ́ lo lè lò láti fi kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. O sì lè pe gbogbo ìdílé ẹ tàbí kó o pe àwọn ọ̀rẹ́ ẹ wá síbi ìkẹ́kọ̀ọ́ náà.

Kí Nìdí Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kì í Fi Lo Àgbélébùú Nínú Ìjọsìn?

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé Kristẹni ni wá, a kì í lo àgbélébùú nínú ìjọsìn wa. Kí nìdí?

Kí Nìdí Tí Ọ̀nà Tí Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gbà Ń Ṣe Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa Fi Yàtọ̀ sí Ti Àwọn Ẹlẹ́sìn Tó Kù?

Wọ́n tún ń pè é ní Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa tàbí Ìrántí Ikú Kristi, òun ni ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣe pàtàkì jù lọ sí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. Wo ohun tí Bíbélì sọ nípa rẹ̀.

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Ṣe Àmúlùmálà Ìgbàgbọ́?

Kí ni Bíbélì sọ tí wọ́n lè fi dáhùn ìbéèrè yìí?

Ṣé Bíbélì Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Yàtọ̀?

Tó o bá lo oríṣiríṣi ìtumọ̀ Bíbélì làti fi kẹ́kọ̀ọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, wà á túbọ̀ lóye ohun tó ò ń kọ́. Ohun mẹ́ta kan wà nípa Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tó lè mú kó o fẹ́ lò ó láti kẹ́kọ̀ọ́.

Ṣé Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Péye?

Kí ló dé tí Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun fi yàtọ̀ sáwọn ìtumọ̀ Bíbélì tó kù?

Ki Nidi Ti Awon Elerii Jehofa Ki I Fi I Lowo si Iselu?

Nje ota alaafia ni awa Elerii Jehofa bi a ki i se lowo si iselu?

Kí Nìdí Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kì Í Fi Í Jagun?

Jákèjádò ayé ni wọ́n ti mọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà pé a kì í lọ́wọ́ sí ogun. Kọ́ nípa ìdí tí a kì í fi í lọ́wọ́ sí ogun.

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Ṣèrànwọ́ Nígbà Àjálù?

Tí àjálù bá ṣẹlẹ̀, wo bá a ṣe ń ran àwọn ará wa lọ́wọ́, títí kan àwọn míì tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà.

Ṣé Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tako Gbígba Abẹ́rẹ́ Àjẹsára?

Ìlànà Bíbélì méjì kan wà tá a lè ronú lé tá a bá fẹ́ pinnu bóyá ká gba abẹ́rẹ́ àjẹsára tàbí ká má ṣe bẹ́ẹ̀.

Ojú Wo Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Fi Ń Wo Ẹ̀kọ́ Ìwé?

Àwọn ìlànà Bíbélì wo làwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń tẹ̀ lé tá a bá fẹ́ ṣe ìpinnu lórí ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́ ìwé?

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Fipá Mú Káwọn Ọmọ Wọn Ṣe Ẹ̀sìn Wọn?

Ó wu àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà pé káwọn ọmọ wọn gbé ìgbésí ayé tó dáa, ohun tí ọ̀pọ̀ òbí sì fẹ́ fáwọn ọmọ wọn náà nìyẹn. Ohun tí wọ́n gbà pé ó máa ṣe àwọn ọmọ wọn láǹfààní ni wọ́n fi ń kọ́ wọn.

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Tú Ìdílé Ká Ni àbí Wọ́n Ń Mú Kí Ìdílé Wà Níṣọ̀kan?

Wọ́n máa ń fẹ̀sùn kan àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà nígbà míì pé wọ́n ń tú ìdílé àwọn èèyàn ká. Àmọ́ ṣé àwọn Ẹlẹ́rìí ló ń fa èdèkòyédè yìí lóòótọ́?

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Òfin tí Wọ́n Máa Ń Tẹ̀ Lé tí Wọ́n Bá Ń Fẹ́ra Sọ́nà?

Ṣe eré ìnàjú lásán làwọn tó ń fẹ́ra sọ́nà ń bára wọn ṣe àbí ó jù bẹ́ẹ̀ lọ?

Ojú Wo Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Fi Ń Wo Ìkọ̀sílẹ̀?

Ṣé àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń ran àwọn tọkọtaya tó bá níṣòro nínú ìgbéyàwó wọn lọ́wọ́? Ṣé ó di dandan káwọn alàgbà ìjọ fọwọ́ sí i tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan bá fẹ́ kọ ìyàwó tàbí ọkọ rẹ̀ sílẹ̀?

Ṣé Ó Láwọn Fíìmù, Ìwé Tàbí Orin Tẹ́yin Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ò Gbọ́dọ̀ Gbádùn?

Àwọn ìlànà pàtàkì wo ló yẹ kí Kristẹni kan tẹ̀ lé tó bá fẹ́ yan eré ìnàjú tó máa wò?

Kí Nìdí Táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kì Í Ṣe Àwọn Ayẹyẹ Kan?

Wo bá a ṣe dáhùn ìbéèrè pàtàkì mẹ́ta nípa àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó bá di ọ̀rọ̀ ayẹyẹ àtàwọn àjọ̀dún táwọn èèyàn máa ń ṣe.

Kí Ló Dé Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kì Í Ṣe Kérésìmesì?

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọ̀pọ̀ èèyàn mọ ibi tí Kérésìmesì ti ṣẹ̀ wá, síbẹ̀ wọ́n ń ṣe é. Wo ìdí táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà kì í fi í ṣe é.

Kí Nìdí Tí Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kì Í Fí Ṣe Ayẹyẹ Ọjọ́ Ìbí?

Gbé àwọn kókó mẹ́rin nípa ayẹyẹ ọjọ́ ìbí tó jẹ́ ká mọ̀ pé Ọlọ́run kò nífẹ̀ẹ́ sí i yẹ̀ wò.

Báwo Ni Ìgbéyàwó Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣe Máa Ń Rí?

Bí ẹnì kọ̀ọ̀kan ṣe máa ṣe ìgbéyàwó tiẹ̀ lè yàtọ̀, ṣùgbọ́n ohun pàtàkì kan wà tó máa ń jọra nínú gbogbo wọn.

Kí Nìdí Tí Ọ̀nà Tí Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gbà Ń Ṣe Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa Fi Yàtọ̀ sí Ti Àwọn Ẹlẹ́sìn Tó Kù?

Wọ́n tún ń pè é ní Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa tàbí Ìrántí Ikú Kristi, òun ni ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣe pàtàkì jù lọ sí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. Wo ohun tí Bíbélì sọ nípa rẹ̀.

Kí Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gbà Gbọ́ Lórí Ọ̀rọ̀ Ìsìnkú?

Ohun táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà gbà gbọ́ nípa ikú, tó sì dá wọn lójú ló jẹ́ kí wọ́n pinnu láti máa ṣe ìsìnkú wọn bí wọ́n ṣe ń ṣe é. Àwọn ìlànà wo wá ni wọ́n ń tẹ̀ lé tí wọ́n fi ń ṣèpinnu?

Ṣé Kristẹni Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Jọ̀wọ́ ṣàgbéyẹ̀wò bí a ṣe yàtọ̀ sí àwọn míì tí wọ́n ń pè ní Kristẹni.

Ṣé Ẹlẹ́sìn Pùròtẹ́sítáǹtì Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Ohun méjì tó fi ìyàtọ̀ sáàárín àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti àwọn tí wọ́n ń pè ní Kristẹni àmọ́ tí kì í ṣe ẹlẹ́sìn Kátólíìkì.

Ṣé Ẹ̀ya Ìsìn Amẹ́ríkà ni Ẹ̀sìn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Ṣàgbéyẹ̀wò kókó mẹ́rin nípa ètò tó kárí ayé yìí.

Ṣé Ẹgbẹ́ Zionism Ni Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

A gbé ìgbàgbọ́ wa ka Ìwé Mímọ́ tí kì í gbé ìran èèyàn kan ga ju òmíràn lọ.

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Mélòó Ló Wà Kárí Ayé?

Wo bá a ṣe máa ń ka iye wa nínú àwọn ìjọ wa kárí ayé.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Di Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Mátíù 28:19, 20 mẹ́nu ba ohun mẹ́ta.

Tí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Bá Ń Kọ́ Mi Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, Ṣé Dandan Ni Kí N Di Ara Wọn?

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń kọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn kárí ayé lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì láìgbowó. Àmọ́ tá a bá ń kọ́ ẹ lẹ́kọ̀ọ́, ṣé dandan ni kó o di Ẹlẹ́rìí Jèhófà?

Ǹjẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Yẹra Fún Àwọn Tí Kò Ṣe Ẹ̀sìn Wọn Mọ́?

Nígbà míì, ó máa ń pọn dandan pé ká yọ ẹnì kan lẹ́gbẹ́, èyí sì lè ran irú ẹni bẹ́ẹ̀ lọ́wọ́ láti pa dà sínú ìjọ.