Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Nípa Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

O máa ń rí wa tá a bá ń wàásù. O ti lè gbọ́ nípa wa nínú ìròyìn tàbí lẹ́nu àwọn kan. Àmọ́ ṣé o mọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lóòótọ́?

O tún lè wo: Kí Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Gbà Gbọ́?

Ohun Tá A Gbà Gbọ́ àti Iṣẹ́ Wa

Ìbéèrè Táwọn Èèyàn Máa Ń Béèrè Nípa Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Wo ìdáhùn sáwọn ìbéèrè tó ṣeéṣe kó o ti béèrè nípa wa.

Ìrírí Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Kọ́ nípa bí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe ń gbìyànjú láti fi Bíbélì darí ohun tí wọ́n ń rò, ọ̀rọ̀ wọn àti ìṣe wọn.

Ohun Tí Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ń Ṣe

Orílẹ̀-èdè tó lé ní igba àti ọgbọ̀n [230] là ń gbé, ibi tá a ti wá yàtọ̀ síra, àṣà ìbílẹ̀ wa ò sì bára mu. O lè ti rí i pé a máa ń wàásù, àmọ́ ìyẹn nìkan kọ́ là ń ṣe, a tún máa ń ṣèrànwọ́ fáwọn èèyàn láwùjọ láwọn ọ̀nà pàtàkì míì.

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Mọ̀ nípa ẹgbẹ́ ará wa kárí ayé.

Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Tá À Ń Ṣe Lọ́fẹ̀ẹ́

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?—Èyí Tó Gùn

Bíbélì ń ran ọ̀pọ̀ mílíọ̀nù èèyàn kárí ayé lọ́wọ́ láti rí ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè pàtàkì nípa ìgbésí ayé. Ṣé ìwọ náà á fẹ́ jẹ́ ọ̀kan lára wọn?

Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?

Níbi gbogbo kárí ayé làwọn èèyàn ti mọ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tí wọ́n máa ń ṣe fáwọn èèyàn lọ́fẹ̀ẹ́. Wo bí wọ́n ṣe máa ń ṣe é.

Ṣé O Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá

O lè mọ̀ sí i nípa Bíbélì tàbí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.

Ìpàdé àti Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì

Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba?

Wo bó ṣe máa ń rí tá a bá wà nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba.

Lọ sí ìpàdé ìjọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Wàá mọ ohun tá a máa ń ṣe láwọn ìpàdé wa, wàá sì mọ ibi tá a ti ń ṣèpàdé tó sún mọ́ ẹ.

Ìrántí Ikú Jésù

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà fẹ́ kó o wá síbi Ìrántí Ikú Jésù tá a máa ṣe ní March 24, 2024.

Ẹ̀ka Ọ́fíìsì

Kàn sí Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Ìsọfúnni nípa bí ẹ ṣe lè kàn sí àwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jákèjádò ayé.

Ìbẹ̀wò sí Bẹ́tẹ́lì

O lè wá ibì kan tó sún mọ́ ẹ tó o lè ṣèbẹ̀wò sí.

Ibo Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Ń Rówó Tí Wọ́n Ń Ná?

A ò kì í gba owó báwọn oníṣọ́ọ̀ṣì ṣe ń gba owó.

Àwọn Wo Ló Ń Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà Lóde Òní?

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà wà kárí ayé, oríṣiríṣi ẹ̀yà la ti wá, àṣà ìbílẹ̀ wa sì yàtọ̀ síra. Kí ló mú kí gbogbo wa wà níṣọ̀kan?

Ìsọfúnni Nípa Wa—Kárí Ayé

  • 239—Iye àwọn ilẹ̀ tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ń jọ́sìn

  • 8,699,048—Iye àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

  • 5,666,996—Iye àwọn èèyàn tí à ń kọ́ ní ẹ̀kọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́

  • 19,721,672—Iye àwọn tó wá sí Ìrántí Ikú Kristi tí à ń ṣe lọ́dọọdún

  • 117,960—Iye ìjọ