Ìsọfúnni Ṣókí—Papua New Guinea
- 10,763,000—Iye àwọn èèyàn
- 5,843—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 164—Iye àwọn ìjọ
- 2,071—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Warren Reynolds: Inú Mi Dùn Pé Ohun Tó Nítumọ̀ Ni Mo Fayé Mi Ṣé
Warren àti Leann ìyàwó ẹ̀ ti rí bí Jèhófà ṣe máa ń kọ́ wa ká lè ṣàṣeyọrí lẹ́nu iṣẹ́ èyíkéyìí tó bá fún wa, tá a sì gbà láti ṣe.
LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA
Ọkọ̀ Ojú Omi Lightbearer Tan Ìmọ́lẹ̀ Òtítọ́ Dé Ilẹ̀ Éṣíà
Láìka àtakò sí, àwọn kéréje tó wà nínú ọkọ̀ ojú omi Lightbearer fi ìgboyà fún irúgbìn Ìjọba Ọlọ́run ní ọ̀pọ̀ ilẹ̀ tó láwọn èrò tó pọ̀ gan-an tí wọ́n ń gbé ibẹ̀.

