Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Burkina Faso

  • Manga, Burkina Faso​—Wọ́n ń wàásù ní àsìkò tí wọ́n ń ká òwú

Ìsọfúnni Ṣókí—Burkina Faso

  • 24,075,000—Iye àwọn èèyàn
  • 2,120—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 57—Iye àwọn ìjọ
  • 12,080—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Ìwọ̀ Oòrùn Áfíríkà

Kí lóhun tó mú kí àwọn kan fi ilẹ̀ Yúróòpù sílẹ̀ lọ sí ilẹ̀ Áfíríkà? Kí ló sì ti jẹ́ àbájáde ìgbésẹ̀ tí wọ́n gbé yìí?

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Sísún Mọ́ Ọlọ́run Dára fún Mi

Nígbà tí Sarah Maiga pé ọmọ ọdún mẹ́sàn-án, kò ga ju bó ṣe wà lọ mọ́, àmọ́ ó ń dàgbà sí i nípa tẹ̀mí.