Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Liberia

  • Nítòsí Monrovia, Liberia​—Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń fún ẹnì kan ní ìwé àṣàrò kúkúrú Igbesi-aye ninu Aye Titun alalaafia kan

Ìsọfúnni Ṣókí—Liberia

  • 5,731,000—Iye àwọn èèyàn
  • 9,225—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 159—Iye àwọn ìjọ
  • 659—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Jèhófà Fún Wa Lókun Lákòókò Ogun àti Lákòókò Àlàáfíà

Paul àti Anne Crudass sọ bí Jèhófà ṣe fún wọn lókun lákòókò ogun àti nígbà ìṣòro.