Ìsọfúnni Ṣókí—Lesotho
- 2,363,000—Iye àwọn èèyàn
- 4,594—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 83—Iye àwọn ìjọ
- 537—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

Abúlé Setibing, Lesotho—Wọ́n ń fi èdè Sesotho sọ ohun tó wà nínú Bíbélì fún ẹnì kan
Bokong, Lesotho—Wọ́n ń fi ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ lọni