Ìsọfúnni Ṣókí—Greenland
- 57,000—Iye àwọn èèyàn
- 139—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 5—Iye àwọn ìjọ
- 422—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún


Oqaatsut, Greenland—Wọ́n ń bá ìdílé kan tí wọ́n jẹ́ ọmọ ilẹ̀ yìí sọ̀rọ̀ látinú Bíbélì