Ìsọfúnni Ṣókí—Mali
- 25,199,000—Iye àwọn èèyàn
- 366—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 6—Iye àwọn ìjọ
- 73,897—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Josette Garcia: Ọ̀pọ̀ Ọdún Ni Mo Fi Wàásù ní Ọ̀kan Lára Àwọn Orílẹ̀-Èdè tí Ojú Ọjọ́ Ibẹ̀ Gbóná Jù Láyé
Ọ̀pọ̀ ìṣòro ni Josette kojú ní Mali, àmọ́ ó láyọ̀ ní gbogbo ọdún tó fi ṣe aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe àti míṣọ́nnárì níbẹ̀.

