Ìsọfúnni Ṣókí—Madagascar
- 32,741,000—Iye àwọn èèyàn
- 45,673—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 865—Iye àwọn ìjọ
- 734—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Madagásíkà
Ẹ jẹ́ ká mọ díẹ̀ lára àwọn akéde tó ṣí lọ sórílẹ̀-èdè Madagásíkà kí wọ́n lè wàásù ìhìn rere jákèjádò orílẹ̀-èdè yìí.

