Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

French Guiana

Ìsọfúnni Ṣókí—French Guiana

  • 292,000—Iye àwọn èèyàn
  • 3,045—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 43—Iye àwọn ìjọ
  • 98—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÍRÍ

Ìrìn Àjò Lágbègbè Odò Maroni

Àwọn Ẹlẹ́rìí mẹ́tàlá (13) ń múra láti rìnrìn àjò, kí wọn lè wàásù Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run fún àwọn tó ń gbé nínú igbó kìjikìji Amazon tó wà ní Gúúsù Amẹ́ríkà.