Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Belgium

  • Jabbeke, Belgium​—Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ Bíbélì ní ibùdókọ̀ kan lójú ọ̀nà E40 Trans-European Motorway

Ìsọfúnni Ṣókí—Belgium

  • 11,826,000—Iye àwọn èèyàn
  • 26,746—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 335—Iye àwọn ìjọ
  • 446—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ

Ibi Àfihàn Bíbélì Ní Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Belgium Ṣàfihàn Ìsapá Táwọn Èèyàn Ṣe Láti Pa Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Mọ́

Wọ́n túmọ̀ Bíbélì, wọ́n sì tẹ̀ ẹ́ láìka àtakò àti ikú sí.