Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Nepal

  • Tharpu Village, Nepal—Wọ́n ń bá àgbẹ̀ kan tó ń sọ èdè Tamang sọ̀rọ̀ nípa Bíbélì

Ìsọfúnni Ṣókí—Nepal

  • 29,876,000—Iye àwọn èèyàn
  • 3,001—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 62—Iye àwọn ìjọ
  • 10,103—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

JÍ!

“Irú Ìfẹ́ Yìí Wú Wa Lórí Gan-an Ni”

Lọ́jọ́ Saturday, April 25, 2015, ìmìtìtì ilẹ̀ tó lágbára kan ṣọṣẹ́ ní orílẹ̀-èdè Nepal. Lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ yìí, àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà fi hàn pé Kristẹni tòótọ́ gbọ́dọ̀ máa fìfẹ́ hàn

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú

Ọ̀pọ̀ àwọn arábìnrin tó ti sìn nílẹ̀ òkèèrè ló kọ́kọ́ lọ́ tìkọ̀ kí wọ́n tó lọ. Àmọ́, kí ló mú kí wọ́n ṣọkàn akin? Kí ni wọ́n sì ti kọ́ lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn wọn lórílẹ̀-èdè mí ì?