Ìsọfúnni Ṣókí—Zambia
- 21,177,000—Iye àwọn èèyàn
- 284,792—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 3,908—Iye àwọn ìjọ
- 84—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Dayrell Sharp: Jèhófà Ni Ò Jẹ́ Ká Fà Sẹ́yìn
Láìka àwọn ìṣòro tí wọ́n kojú sí, Dayrell àti Susanne Sharp ran àwọn tó lé ní àádóje lọ́wọ́ láti ṣèrìbọmi.

