Ìsọfúnni Ṣókí—Mozambique
- 35,632,000—Iye àwọn èèyàn
- 109,531—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 2,072—Iye àwọn ìjọ
- 345—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ
Àpéjọ Agbègbè Lórí Tẹlifíṣọ̀n àti Rédíò
A gbé àpéjọ agbègbè 2020 sórí ìkànnì, àmọ́ ọ̀pọ̀ ní Màláwì àti Mòsáńbíìkì ò ní Íńtánẹ́ẹ̀tì. Báwo wá ni wọ́n ṣe wo àpéjọ náà?

