ÌRÒYÌN

Mozambique

Yorùbá
Mozambique
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png

Mozambique

 

2016-05-04

MOZAMBIQUE

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Pèsè Ìrànwọ́ Lẹ́yìn Tí Omíyalé Tó lágbára Ṣẹlẹ̀ ní Ìlú Mozambique

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń bá a lọ láti pèsè ìrànlọ́wọ́, wọ́n sì ń fáwọn ará ní ìṣírí nípa tẹ̀mí lẹ́yìn tí omíyalé bo apá àríwá àti àárín gbùngbùn ìlú Mozambique.