Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Haiti

Ìsọfúnni Ṣókí—Haiti

  • 11,906,000—Iye àwọn èèyàn
  • 16,750—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 243—Iye àwọn ìjọ
  • 721—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

Iṣẹ́ Ìrànwọ́ Ń Parí Lọ Lẹ́yìn Tí Ìjì Hurricane Matthew Jà ní Haiti

June 2017 ni wọ́n ṣètò láti parí iṣẹ́ ìrànwọ́ tí wọ́n ń ṣe lọ́wọ́ yìí.

ÌRÒYÌN

Ìjọba Haiti fún Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Àmì Ẹ̀yẹ Torí Bí Wọ́n Ṣe Ran Àwọn Aláàbọ̀ Ara Lọ́wọ́

Ọ́fíìsì Akọ̀wé Ìjọba Tó Ń Rí sí Ọ̀rọ̀ Àwọn Aláàbọ̀ Ara ní Haiti fún Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní Haiti lámì ẹ̀yẹ, torí pé wọ́n mọrírì bí wọ́n ṣe ń sapá láti ran àwọn aláàbọ̀ ara lọ́wọ́.