Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Zimbabwe

  • Matobo District, Zimbabwe​—Wọ́n ń wàásù láti ilé dé ilé

Ìsọfúnni Ṣókí—Zimbabwe

  • 15,923,000—Iye àwọn èèyàn
  • 55,516—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 997—Iye àwọn ìjọ
  • 296—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Mo Jẹ́ Kí Jèhófà Tọ́ Mi Sọ́nà

Ìtàn Ìgbésí Ayé: Keith Eaton

BÁ A ṢE Ń NÁ OWÓ TẸ́ Ẹ FI Ń ṢÈTỌRẸ

A Pèsè Ìrànwọ́ Fáwọn Tí Àjálù Ṣẹlẹ̀ Sí

Lọ́dún iṣẹ́ ìsìn 2020, àrùn Corona àtàwọn àjálù míì mú kí nǹkan nira fún ọ̀pọ̀ àwọn ará wa. Báwo la ṣe ràn wọ́n lọ́wọ́?