Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Estonia

  • Ní nǹkan bí ọdún 1930 nílùú Tallinn, lórílẹ̀-èdè Estonia, Arákùnrin Kaarlo Harteva ń múra láti gbé àsọyé Bíbélì kan sáfẹ́fẹ́ lórí rédíò, àwọn èèyàn sì máa gbọ́ ọ ní Estonia, apá ìwọ̀ oòrùn Rọ́ṣíà àti orílẹ̀-èdè Scandinavia

Ìsọfúnni Ṣókí—Estonia

  • 1,370,000—Iye àwọn èèyàn
  • 4,118—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 54—Iye àwọn ìjọ
  • 334—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

IṢẸ́ ÌTẸ̀WÉ

Àwọn Èèyàn Orílẹ̀-Èdè Estonia Mọyì “Iṣẹ́ Ńlá” Tá A Ṣe

Bíbélì Ìtúmọ̀ Ayé Tuntun wà lára àwọn ìwé tó fakọ yọ jù lọ tí wọ́n mú, tí wọ́n sì fún ní Àmì Ẹ̀yẹ Ìwé Tó Dára Jù Lọ ní Orílẹ̀-Èdè Estonia lọ́dún 2014.

ILÉ ÌṢỌ́

“Ohun Tó Ti Ṣẹlẹ̀ Ti Ṣẹlẹ̀ Àmọ Ẹ Fi Ṣàríkọ́gbọ́n”

Ní April 1, 1951, Ọgọ́ọ̀rọ̀rún Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ni wọ́n lé kúrò nílùú Estonia lọ sí Siberia. Kí nìdí?