Ìsọfúnni Ṣókí—Curaçao
- 156,000—Iye àwọn èèyàn
- 1,930—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 24—Iye àwọn ìjọ
- 81—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún


Agbègbè Punda ní Willemstad, lórílẹ̀-èdè Curaçao—Wọ́n ń fi fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? han ẹnì kan
Agbègbè Punda ní Willemstad, lórílẹ̀-èdè Curaçao—Wọ́n ń ka ẹsẹ Bíbélì kan tá a tọ́ka sí nínú ìwé pẹlẹbẹ Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!
Agbègbè Punda ní Willemstad, lórílẹ̀-èdè Curaçao—Wọ́n ń wàásù láti ilé dé ilé