Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Switzerland

  • Zurich, Switzerland​—Wọ́n ń fi àtẹ́ tí wọ́n gbé dání wàásù ọ̀rọ̀ inú Bíbélì

  • Montreux, Switzerland​—Wọ́n ń fi ìwé tó dá lórí Bíbélì lọni nítòsí Château de Chillon

  • Lucerne, Switzerland​—Wọ́n ń fi fídíò kan tó dá lórí Bíbélì hàn látorí jw.org

  • Àgbègbè Lavaux, ní Switzerland​—Wọ́n ń sọ ohun tó wà nínú Bíbélì

Ìsọfúnni Ṣókí—Switzerland

  • 9,049,000—Iye àwọn èèyàn
  • 20,352—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 244—Iye àwọn ìjọ
  • 447—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

LÁTINÚ ÀPAMỌ́ WA

Ohun Tó Dáa Jù Ni Wọ́n Fi Ránṣẹ́

Báwo làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe ran àwọn ará wọn ní Jámánì lọ́wọ́ gbàrà tí Ogun Àgbáyé Kejì parí?