Ìsọfúnni Ṣókí—Chile
- 20,207,000—Iye àwọn èèyàn
- 88,664—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 1,024—Iye àwọn ìjọ
- 229—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ÌRÒYÌN
Àwọn Ẹlẹ́rìí Ṣètò Ìrànwọ́ fún Àwọn Tí Jàǹbá Omíyalé Ṣẹlẹ̀ sí Ní Chile
Gbàrà tí àjálù omíyalé ṣẹlẹ̀ àti ilẹ̀ ríri ṣẹlẹ̀ lórílẹ̀-èdè Chile, làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà nílùú Copiapó ti ṣètò àwùjọ tó ń ṣètò ìrànwọ́ fún àwọn tí àjálù ṣẹlẹ̀.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Ọmọbìnrin Kan Lo Ìdánúṣe
Kà nípa bí ọmọbìnrin kan lórílẹ̀-èdè Chile tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́wàá ṣe ṣiṣẹ́ kára láti pé gbogbo àwọn tó ń sọ èdè Mapudungun níléèwé rẹ̀ wá síbi ìṣẹ̀lẹ̀ pàtàkì kan.

