Àwọn Ohun Tó Jáde Láìpẹ́ Yìí
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Nǹkan Ṣe Túbọ̀ Ń Gbówó Lórí Kárí Ayé?
Kí nìdí tí ipò ọrọ̀ ajé fi túbọ̀ ń burú sí i? Báwo ni Bíbélì ṣe lè ràn wá lọ́wọ́?
Ìdílé Aláyọ̀—Máa Ṣiṣẹ́ Kára
Tó o bá kọ́ bó o ṣe lè máa ṣiṣẹ́ kára ní báyìí tó o ṣì jẹ́ ọ̀dọ́, o máa ṣe àṣeyọrí nínú gbogbo nǹkan tó o bá ń ṣe.
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Máa Gbàdúrà?
Ṣé torí kí ara kàn lè tuni léèyàn ṣe máa ń gbàdúrà ni, àbí ó kọjá ìyẹn?
Ṣé Àwa Èèyàn Lè Fòpin sí Ogun àti Rògbòdìyàn?
Àwọn èèyàn ṣì ń wá bí wọ́n ṣe máa fòpin sí ogun àti rògbòdìyàn, àmọ́ ṣé wọ́n máa ṣàṣeyọrí?
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ogun Tí Wọ́n Á Fi Bọ́ǹbù Átọ́míìkì Jà?
Kò síbì kankan tí Bíbélì ti sọ̀rọ̀ nípa ogun tí wọ́n á fi bọ́ǹbù átọ́míìkì jà. Àmọ́ ó sọ̀rọ̀ nípa ìwà táwọn èèyàn á máa hù àtohun tó lè mú kí irú ogun yìí jà àti bí Ọlọ́run ṣe máa fòpin sí i.
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ọ̀rẹ́?
Àwọn ọ̀rẹ́ gidi máa ń jẹ́ ká níwà tó dáa. Fọgbọ́n yan àwọn ọ̀rẹ́ rẹ!
Ìdílé Aláyọ̀—Jẹ́ Ẹni Tó Ṣeé Gbọ́kàn Lé
Táwọn òbí rẹ bá gbọ́kàn lé ẹ, ìyẹn máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ bó o ṣe túbọ̀ ń dàgbà.
Bá A Ṣe Lè Dènà Àrùn
Kéèyàn máa ṣàìsàn lóòrèkóòrè máa ń ṣàkóbá fún ìlera rẹ. Àwọn ọ̀nà wo lo lè gbà dènà rẹ̀?
Bó O Ṣe Lè Ní Ìtẹ́lọ́rùn àti Ìfọ̀kànbalẹ̀
Wàá rí mẹ́rin lára àwọn ìlànà Bíbélì tó ń ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ kí wọ́n lè máa láyọ̀, kí ọkàn wọn sì túbọ̀ balẹ̀.
Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Tí Ọkàn Gbogbo Èèyàn Máa Balẹ̀
A ò lágbára láti yanjú gbogbo ohun tó ń fa àìbalẹ̀ ọkàn. Àmọ́ Jèhófà lè yanjú ẹ̀.

