Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ?

Àwọ̀ Ẹyẹ Tí Kì Í Ṣá

Àwọ̀ Ẹyẹ Tí Kì Í Ṣá

Kí nìdí tí ìyẹ́ ọ̀pọ̀ ẹyẹ kì í ṣá, tó máa ń dán gbinrin fún ọ̀pọ̀ ọdún, nígbà tó jẹ́ pé kì í pẹ́ tí ọ̀dà àti aṣọ táwa èèyàn ṣe fi máa ń ṣá?