Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

A7-B

Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Ìbẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Jésù

ÀKÓKÒ

IBI

ÌṢẸ̀LẸ̀

MÁTÍÙ

MÁÀKÙ

LÚÙKÙ

JÒHÁNÙ

29, ìgbà ìwọ́wé

Odò Jọ́dánì, bóyá ní Bẹ́tánì tàbí nítòsí ibẹ̀, ní ìsọdá Jọ́dánì

Jésù ṣe ìrìbọmi, Ọlọ́run sì fi ẹ̀mí mímọ́ yàn án; Jèhófà sọ pé Ọmọ òun ni, ó sì tẹ́wọ́ gbà á

3:13-17

1:9-11

3:21-38

1:32-34

Aginjù Jùdíà

Èṣù dán an wò

4:1-11

1:12, 13

4:1-13

 

Bẹ́tánì ní ìsọdá Jọ́dánì

Jòhánù Arinibọmi fi Jésù hàn pé ó jẹ́ Ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run; àwọn ọmọ ẹ̀yìn àkọ́kọ́ dara pọ̀ mọ́ Jésù

     

1:15, 29-51

Kánà ti Gálílì; Kápánáúmù

Iṣẹ́ ìyanu àkọ́kọ́ níbi ìgbéyàwó, ó sọ omi di wáìnì; ó lọ sí Kápánáúmù

     

2:1-12

30, Ìrékọjá

Jerúsálẹ́mù

Ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́

     

2:13-25

Ó bá Nikodémù sọ̀rọ̀

     

3:1-21

Jùdíà; Áínónì

Ó lọ sí ìgbèríko Jùdíà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ ń ṣèrìbọmi fún àwọn èèyàn; ẹ̀rí tí Jòhánù jẹ́ kẹ́yìn nípa Jésù

     

3:22-36

Tìbéríà; Jùdíà

Wọ́n fi Jòhánù sẹ́wọ̀n; Jésù lọ sí Gálílì

4:12; 14:3-5

6:17-20

3:19, 20

4:1-3

Síkárì, ní Samáríà

Nígbà tó ń lọ sí Gálílì, ó kọ́ àwọn ará Samáríà

     

4:4-43

Aginjù Jùdíà