Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

B5

Àgọ́ Ìjọsìn àti Àlùfáà Àgbà

Àwọn Ohun Tó Wà ní Àgọ́ Ìjọsìn

  1. 1 Àpótí (Ẹk 25:10-22; 26:33)

  2. 2 Aṣọ Ìdábùú (Ẹk 26:31-33)

  3. 3 Òpó fún Aṣọ Ìdábùú (Ẹk 26:31, 32)

  4. 4 Ibi Mímọ́ (Ẹk 26:33)

  5. 5 Ibi Mímọ́ Jù Lọ (Ẹk 26:33)

  6. 6 Aṣọ Tí Wọ́n Ta (Ẹk 26:36)

  7. 7 Òpó fún Aṣọ Tí Wọ́n Ta (Ẹk 26:37)

  8. 8 Ìtẹ́lẹ̀ Oníhò Tí Wọ́n Fi Bàbà Ṣe (Ẹk 26:37)

  9. 9 Pẹpẹ Tùràrí (Ẹk 30:1-6)

  10. 10 Tábìlì Búrẹ́dì Àfihàn (Ẹk 25:23-30; 26:35)

  11. 11 Ọ̀pá Fìtílà (Ẹk 25:31-40; 26:35)

  12. 12 Aṣọ Àgọ́ Tí Wọ́n Fi Aṣọ Ọ̀gbọ̀ Ṣe (Ẹk 26:1-6)

  13. 13 Aṣọ Àgọ́ Tí Wọ́n Fi Irun Ewúrẹ́ Ṣe (Ẹk 26:7-13)

  14. 14 Ìbòrí Tí Wọ́n Fi Awọ Àgbò Ṣe (Ẹk 26:14)

  15. 15 Ìbòrí Tí Wọ́n Fi Awọ Séálì Ṣe (Ẹk 26:14)

  16. 16 Férémù (Ẹk 26:15-18, 29)

  17. 17 Ìtẹ́lẹ̀ Oníhò Tí Wọ́n Fi Fàdákà Ṣe, Tó Wà Lábẹ́ Férémù (Ẹk 26:19-21)

  18. 18 Ọ̀pá Gbọọrọ (Ẹk 26:26-29)

  19. 19 Ìtẹ́lẹ̀ Oníhò Tí Wọ́n Fi Fàdákà Ṣe (Ẹk 26:32)

  20. 20 Bàsíà Bàbà (Ẹk 30:18-21)

  21. 21 Pẹpẹ Ẹbọ Sísun (Ẹk 27:1-8)

  22. 22 Àgbàlá (Ẹk 27:17, 18)

  23. 23 Ẹnu Ọ̀nà (Ẹk 27: 16)

  24. 24 Àwọn Aṣọ Ìdábùú Tí Wọ́n Ta (Ẹk 27:9-15)

Àlùfáà Àgbà

Ẹ́kísódù orí 28 ṣàlàyé bí aṣọ àlùfáà àgbà ní Ísírẹ́lì ṣe rí