Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

A7-Ẹ

Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nínú Ìgbésí Ayé Jésù—Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tó Ta Yọ Tí Jésù Ṣe ní Gálílì (Apá Kẹta) àti ní Jùdíà

ÀKÓKÒ

IBI

ÌṢẸ̀LẸ̀

MÁTÍÙ

MÁÀKÙ

LÚÙKÙ

JÒHÁNÙ

32, lẹ́yìn Ìrékọjá

Òkun Gálílì; Bẹtisáídà

Jésù wọkọ̀ ojú omi lọ sí Bẹtisáídà, ó kìlọ̀ nípa ìwúkàrà àwọn Farisí; ó la ojú ọkùnrin afọ́jú

16:5-12

8:13-26

   

Agbègbè Kesaríà ti Fílípì

Àwọn kọ́kọ́rọ́ Ìjọba Ọlọ́run; ó sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú àti àjíǹde rẹ̀

16:13-28

8:27–9:1

9:18-27

 

Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ ní Òkè Hámónì

Ìyípadà ológo; Jèhófà sọ̀rọ̀

17:1-13

9:2-13

9:28-36

 

gbègbè Kesaríà ti Fílípì

Ó lé ẹ̀mí èṣù jáde lára ọmọkùnrin kan

17:14-20

9:14-29

9:37-43

 

Gálílì

Ó tún sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀

17:22, 23

9:30-32

9:43-45

 

Kápánáúmù

Ó fi owó tí wọ́n rí lẹ́nu ẹja san owó orí

17:24-27

     

Ẹni tó tóbi jù nínú Ìjọba Ọlọ́run; àpèjúwe àgùntàn tó sọ nù àti ti ẹrú tí kò dárí jini

18:1-35

9:33-50

9:46-50

 

Gálílì sí Samáríà

Ó ń lọ sí Jerúsálẹ́mù, ó sọ fáwọn ọmọ ẹ̀yìn pé kí wọ́n yááfì gbogbo nǹkan torí Ìjọba Ọlọ́run

8:19-22

 

9:51-62

7:2-10

Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Tí Jésù Tún Ṣe ní Jùdíà

ÀKÓKÒ

IBI

ÌṢẸ̀LẸ̀

MÁTÍÙ

MÁÀKÙ

LÚÙKÙ

JÒHÁNÙ

32, Àjọyọ̀ Àwọn Àgọ́ Ìjọsìn (tàbí Àtíbàbà)

Jerúsálẹ́mù

Ó kọ́ni níbi Àjọyọ̀ náà; wọ́n rán àwọn òṣìṣẹ́ pé kí wọ́n wá mú un

     

7:11-52

Ó sọ pé “Èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé”; ó la ojú ọkùnrin tí wọ́n bí ní afọ́jú

     

8:12–9:41

Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ ní Jùdíà

Ó rán àwọn 70 jáde; wọ́n pa dà dé tayọ̀tayọ̀

   

10:1-24

 

Jùdíà; Bẹ́tánì

Àpèjúwe ará Samáríà tó nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ̀; ó lọ sí ilé Màríà àti Màtá

   

10:25-42

 

Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ ní Jùdíà

Ó tún kọ́ wọn ní àdúrà àwòṣe; àpèjúwe ọ̀rẹ́ kan tí kò yéé bẹ̀bẹ̀

   

11:1-13

 

Ó fi ìka Ọlọ́run lé ẹ̀mí èṣù jáde; ó tún fún wọn ní àmì Jónà nìkan

   

11:14-36

 

Ó bá Farisí jẹun; ó dẹ́bi fún ìwà àgàbàgebè àwọn Farisí

   

11:37-54

 

Àwọn àpèjúwe: ọkùnrin ọlọ́rọ̀ tó jẹ́ aláìlóye àti ti ìríjú olóòótọ́ náà

   

12:1-59

 

Lọ́jọ́ Sábáàtì, ó wo obìnrin kan tí kò lè nàró sàn; àpèjúwe hóró músítádì àti ti ìwúkàrà

   

13:1-21

 

32, Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́

Jerúsálẹ́mù

Jerúsálẹ́mù Àpèjúwe olùṣọ́ àgùntàn àtàtà àti agbo àgùntàn; àwọn Júù fẹ́ sọ ọ́ lókùúta; ó kọjá sí Bẹ́tánì ní òdìkejì Jọ́dánì

     

10:1-39