Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

A6-A

Àtẹ: Àwọn Wòlíì àti Àwọn Ọba Ilẹ̀ Júdà àti Ísírẹ́lì (Apá Kìíní)

Àwọn Ọba Ìjọba Ẹ̀yà Méjì ti Júdà ní Gúúsù

997 Ṣ.S.K.

Rèhóbóámù: 17 ọdún

980

Ábíjà (Ábíjámù): 3 ọdún

978

Ásà: 41 ọdún

937

Jèhóṣáfátì: 25 ọdún

913

Jèhórámù: 8 ọdún

n. 906

Ahasáyà: 1 ọdún

n. 905

Ọbabìnrin Ataláyà: 6 ọdún

898

Jèhóáṣì: 40 ọdún

858

Amasááyà: 29 ọdún

829

Ùsáyà (Asaráyà): 52 ọdún

Àwọn Ọba Ìjọba Ẹ̀yà Mẹ́wàá ti Ísírẹ́lì ní Àríwá

997 Ṣ.S.K.

Jèróbóámù: 22 ọdún

n. 976

Nádábù: 2 ọdún

n. 975

Bááṣà: 24 ọdún

n. 952

Élà: 2 ọdún

Símírì: ọjọ́ 7 (n. 951)

Ómírì àti Tíbínì: 4 ọdún

n. 947

Ómírì (nìkan): 8 ọdún

n. 940

Áhábù: 22 ọdún

c. 920

Ahasáyà: 2 ọdún

n. 917

Jèhórámù: 12 ọdún

n. 905

Jéhù: 28 ọdún

876

Jèhóáhásì: 14 ọdún

n. 862

Jèhóáhásì àti Jèhóáṣì: 3 ọdún

n. 859

Jèhóáṣì (nìkan): 16 ọdún

n. 844

Jèróbóámù Kejì: 41 ọdún

  • Orúkọ Àwọn Wòlíì

  • Jóẹ́lì

  • Èlíjà

  • Èlíṣà

  • Jónà

  • Émọ́sì